[Lyrics] Barry Jhay – Ejebleje Lyrics

Frank Edward Unlimited 1

Lyrics

Quality over quantity (o pree)
Oò mọ ‘rú ẹ’, ṣọ’ ọ ní ‘rú ẹ?
Ẹjẹblejẹ, ẹ’jẹ ló ń lò, oh no
Ọmọ tó ní ìyá òun ò ní sùn, ohùn gangan ò ní sinmi
And as I dey tẹpá mọ my hustle, ẹ fún Adekunle mi ní Simi
Ara lamọ, ara lamọ (lamọ), a ò mọ ẹni tó fẹ’ ni dénú (ye)
Àbí ẹ ò rí aṣinú, ó fi Bíbélì ka kéwú
Ara lamọ, ara lamọ (lamọ), a ò mọ ẹni tó fẹ ni dénú (ye)
Àbí ẹ ò rí aṣinú, ó fẹ fi Bíbélì ka kéwú

Confirm ni, no be para oh
Control, no be galala
To make money, no be by dragger
Oh-oh-oh, aya-ya
Confirm ni, no be paara oh
Control, no be galala
To make money, no be by dragger
Oh-oh-oh, aya-ya (aya-ya)

Heys, ọmọ tó bá ta féleféle, ẹ gbá ojú ẹ
Ẹ le pa (ẹ le pa), ó le kwà (ó le kwà), oh-uh-oh
Ọmọ tó bá bẹ sí mi, éè ní fara ire lọ, àh
Ajurawalọ, ti ìjàkadì kọ, ìwọ náà mọ

Ẹni bínú mi, ò ní ní sinmi
Ẹ’yin enemies, kakulu fuhi
Yes, I mean dede yín, uh
Mo sorry fún gbo-, gbo yín oh-oh
Mo sorry fún gbogbo yín lọ’kọ’ọ’kan (ah-yeah)

Confirm ni, no be para oh
Control, no be galala
To make money, no be by dragger (yeah, ye)
Oh-oh-oh, aya-ya
Confirm ni, no be paara oh
Control, no be galala
To make money, no be by dragger
Oh-oh-oh, aya-ya

Heys, ọmọ tó bá ta féle-féle, ẹ gbá ojú ẹ
Ẹ le pa (ẹ le pa), ó le kwà (ó le kwà) (anya o)
Ọmọ tó bá bẹ sí mi, éè ní fara ire lọ, àh
Ajurawalọ, ti ìjàkadì kọ, ìwọ náà mọ

Click to Comment

Leave a Reply

.

Designed by Admalic Inc.  BMB © 2024.

I need help with…