[Lyrics] Barry Jhay – My Father My Father Lyrics

Lyrics
Oh-oh-ohh-oh-oh-ohh
Oh-oh-ohh-oh-oh-ohh, ye-ye (Mad-Madaroad)
Oh-oh-ohhh, yeah-yeah, ohh
Yeah, say
I don’t force it
I just let the Spirit lead
‘Cause I know
Yes, I know You are with me all the way
My Father, My Father
Ọlọrun ti ko kí ń yipò padà
Ọrọ ayé mí ọwọ ẹ lọwa
Ìwọ nìkan ní mọ gbẹkẹmilẹ o, ah (ẹru ògo rẹ ńbámí)
Ẹlẹwa Ògo (hm)
Àdàbà Mímọ, jọwọ, balẹ mí o oh-ohh (ẹmi ọmọ rẹ rẹẹ)
Mo tún dúró síwájú rẹ bí mo ṣẹ má ńṣe
Ẹmí-mímọ, jọwọ, wá gbé mí fo o
Mo fẹ ga nínú wọn (gbà mí gbọ)
Má ṣẹ gbàrà lẹwọn, má ṣẹ gbẹkẹlẹ’nìyàn
Ìgbẹ́kẹ̀lẹ ènìyàn asán bansa, yẹ, rẹ o
Má ṣẹ gbàrà lẹwọn, dákun, má ṣẹ gbẹkelẹ’nìyàn
Ìgbẹ́kẹ̀lẹ ènìyàn asán bansa, yeah-oh
Ìrìn yí mọọ, má lọ lofo, ní mo ṣẹ d’ẹsẹ’ Ọlọ́run mí mú o, uh
(Ní mo ṣẹ gbà Ọlọ́run mí mú ṣinṣin)
Bí Olùwà ṣẹ ń sọla ìyẹn nínú ọlá àt’ayo
Bẹ ní yí o tún ṣògo, ohh, Ọlọrun mí ògo
My Father, My Father
Ọlọrun ti ko kí ń yipò padà
Ọrọ ayé mí ọwọ ẹ lọwa
Ìwọ nìkan ní mọ gbẹkẹmilẹ o, ah (ẹru ògo rẹ ńbámí)
Ẹlẹwa Ògo (hm)
Àdàbà Mímọ, jọwọ, balẹ mí o oh-ohh (ẹmi ọmọ rẹ rẹẹ)
Mo tún dúró síwájú rẹ bí mo ṣẹ má ńṣe
Ẹmí-mímọ, jọwọ, wá gbé mí fo o
Mo fẹ ga nínú wọn (gbà mí gbọ)
Má ṣẹ gbàrà lẹwọn, má ṣẹ gbẹkẹlẹ’nìyàn
Ìgbẹ́kẹ̀lẹ ènìyàn asán bansa, yẹ, rẹ o
Má ṣẹ gbàrà lẹwọn, dákun, má ṣẹ gbẹkelẹ’nìyàn
Ìgbẹ́kẹ̀lẹ ènìyàn asán bansa, yeah-oh

Click to Comment

Leave a Reply

.

Designed by Admalic Inc.  BMB © 2024.

I need help with…