[Lyrics] Qdot – Breakfast Lyrics

s
Alágbe (Shocker lo ṣe beat)
Onílù yí jọ- oo
Ọmọ ẹluku mẹdẹ-mẹdẹ, ìmolè àfelẹja
Emi naní, ọmọ-ọmọ Moriamo
Qdot l’orúkọ kọ mí
Wọni oro dákun mà soko, ẹjẹ ńsọ tọwọ mí náà
Ẹdakún, níbo lo wa, nígbà tí mo fojú wina?
Mo badi, ìmolè ní mí
Òyìnbó odún lẹnu mí, torí Ìbílẹ ní mí
Tẹ ba ní ké mú ẹnì àf’ọlá
Labalaba tó ṣẹré ẹ̀gún, aṣọ rẹ mafaya
I’m here for the money, not the fame
Ask about me, I’m making money in the game
B’ologiní bà gún orí ajá, àrí’lé àrọko
Fuck anybody fuckable, I don’t care
Mo dá bí Messi, mo dá bí C’Ronaldo
Mo mọ Sanwo Ayanlu, ẹruku mo bá tó
Lalude gàn o’lẹ p’Abija
Ọmọ Ìbàdàn tó f’èwe sẹnu, ṣọ’le Bodija?
Ẹtakete, berí mí ní orítá Molete, emí kó lé má challenge
Moda, (moda gan)
Àta ní mí, motá (mota gan)
Ìná mí o mẹní tó da, werepe ní mí, ẹma loja
Award onigi, iná ìgi lama fí dá
Fuck your lyrics, he’s on the road, I’m the best
Tába tí àdà, fún àwọn tìwá wọn o dá
Wọni wọn ogbọmí, speaker wọn ní o dá
Mí o need akaba, kí ńto ga t’àlaga
Ká dobalè fún àrá, ìyẹn o ní kamá ga
Punchline fọ wọn lẹ’nu lọ gba-gba-gba
Ẹsẹ’ May Weather mo gbéwá
Dákun, mà lọ faya gbà
Ayangba dangerous
Makinde pá’wó ju Linda Ikeji lọ
Ẹma pá ohùn má gogo, ẹjẹ ń polongo
Ẹṣù lo lorita, Oluweri lo lodò
Don’t near me, I’m bad
Ọmọ àke nígbo, keru bá àrá ọna
Ọmọ má jegi jẹ èniyàn, oríkì Bàbá mí ní
Oka mí lará gàn, o’sho jù Abu Abel
Ṣebi ká rín, kápọ, yíyẹ ní ńyẹni
Ko dẹ ní yẹ yín, ewúré lo má gbà ògo yín
Boku ọwọ kàn àdán, àdán má fí rogi
Kólé burú títí, kí ọmọ àlapatá mí wá jegi
Wọn wípé mariwo larí, pe’égún ńbọ
Nígbà tẹ’gún rí wá gàn, eégún gbọn
Ẹdakún, ṣẹ’ẹyẹ àdán ní (àbí) ẹiyẹ guungún?
Wọni àwọn m’ẹyẹ lápo, ẹiyẹ tún tí kú
Bà rán niṣẹ ẹru, àmà fí tọmọ jẹ
Bàbálawo tí o já, lomá padà toro jẹ
Bí ìṣe kàn o lomọ, ìṣẹ kàn lo ńlọ
Tí o bá jawó lo rí dating, gbé sórí PPP
Wọni, Acapella rẹ dùn, ìwọ dákun má fí ìlù sí (Shocker lo ṣe beat)
Saladi mí, lọ fẹ bámí fí ìru sí
Ogún tí o jẹ, ṣẹ bí ẹwé ẹ loku kàn
Ọba ní mí Alagbe o rẹ bí kán-kán
Kabiesi o (kabiesi o, kabiesi o) (yeah, who’s here?)
Ọmọ Àjànà

Click to Comment

Leave a Reply

.

Designed by Admalic Inc.  BMB © 2024.

I need help with…